Jump to content

Ọ̀rọ̀ oníṣe:Taoheedah: Ìyàtọ̀ láàrin àwọn àtúnyẹ̀wò

Page contents not supported in other languages.
Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Content deleted Content added
Mo kó ìjíròrò yìí wá sí ibi tí ó yẹ kí ó wà
Ìlà 6: Ìlà 6:
==Àkíyèsí pàtàkì==
==Àkíyèsí pàtàkì==
Ẹ káre [[Oníṣe:Taoheeda]], a kí yín kú iṣẹ́ takuntakun, Mo fẹ́ pè yín sí àkíyèsí pàtàkì lórí àwọn àyọkà yín rí ẹ ń dá sílẹ̀. Ẹ ṣe ògbufọ̀ yín dára dára kí ẹ tó ṣẹ̀dá àwọn àyọkà yí sórí Wikipedia èdè Yorùbá, ó ṣe pàtàkì kí ẹ ṣe èyí fún ìdẹsẹ̀ múlẹ̀ iṣẹ́ gbogbo wa. Ẹ ṣeun púpọ̀.[[Oníṣe:Agbalagba|Agbalagba]] ([[Ọ̀rọ̀ oníṣe:Agbalagba|ọ̀rọ̀]]) 22:53, 27 Oṣù Kàrún 2022 (UTC)
Ẹ káre [[Oníṣe:Taoheeda]], a kí yín kú iṣẹ́ takuntakun, Mo fẹ́ pè yín sí àkíyèsí pàtàkì lórí àwọn àyọkà yín rí ẹ ń dá sílẹ̀. Ẹ ṣe ògbufọ̀ yín dára dára kí ẹ tó ṣẹ̀dá àwọn àyọkà yí sórí Wikipedia èdè Yorùbá, ó ṣe pàtàkì kí ẹ ṣe èyí fún ìdẹsẹ̀ múlẹ̀ iṣẹ́ gbogbo wa. Ẹ ṣeun púpọ̀.[[Oníṣe:Agbalagba|Agbalagba]] ([[Ọ̀rọ̀ oníṣe:Agbalagba|ọ̀rọ̀]]) 22:53, 27 Oṣù Kàrún 2022 (UTC)

== Àkíyèsí pàtàkì ==

Oníṣẹ́@[[Oníṣe:Taoheedah|Taoheedah]], mo ṣàkíyèsí wípé púpọ̀ nínú àwọn àyọkà rẹ tí o kọ sí orí Wikipedia èdè Yorùbá ni wọ́n jẹ́ kíkọ sílẹ̀ pẹ̀lú irinṣẹ́ Google Translation. Mo ma gbà ọ́ níyànjú kí o ṣe àtúnṣe tí ó yẹ sí wọn kí wọ́n lè mọ́yán lórí jù báyí lọ. Lásìkò tí o bá ń ṣe èyí, n ó gbà ọ́ níyànjú kí o má ṣe da àyọkà tuntun míràn sílẹ̀ nítorí kí o lè ráyè kọbi ara sí àwọn àtúnṣe rẹ gbogbo. Àpẹẹrẹ irúfẹ́ àwọn àyọkà bẹ́ẹ̀ ni: [[Átẹ́gùn Ooru]], [[Ìmúdọ́gba Àyipàdà Ójú Ọjọ́]] , [[Ipà Àyipada Óju Ọjọ ninu Ẹkọ Ọgbin]], [[Aarun Ómi ati Àyipada Óju Ọjọ]], [[Ìṣilọ ati Àyipada lori Àyika Ágbàyè]], [[Ájálù to ṣẹ̀lẹ nipa Ìfómipamọ ti Gusau]], [[Desmond Màjẹkòdùnmì]] àti bẹ́ẹ̀ bẹ́ẹ̀ lọ.
Àwọn ohun tí a ń retí nínú àwọn àtúnṣe rẹ ni:
#Ṣíṣàmúlò àkọtọ́ gidi lórí àwọn àyọkà rẹ.
# Ṣíṣayípada àwọn ọ̀rọ̀ bíi ''arákùnrin náà'', àti àwọn ohun tó fara pa, ìdí ni pé ìṣọwọ́kọ̀wé yí kò bá ìsọwọ́ kọ ìmọ̀-ọ̀fẹ́ sílẹ̀ mu.
#Lílo àwọn àmì ohùn tó yanjú lórí àwọn àyọkà rẹ àti bẹ́ẹ̀ bẹ́ẹ̀ lọ.
Lákòòtán, ìkìlọ̀ tó wà níbẹ̀ ni wípé bí a kò bá rí àtúnṣe tó lọ́ọ̀rìn lóri àwọn àyọkà wọ̀nyí, a ó dárúkọ wọn fún ìparẹ́ kíákíá. Àwọn àyọkà tó mọ́yán lórí la ń fẹ́ lórí Wikipedia èdè Yorùbá; kìí ṣe danda wìì. O ṣeun púpọ̀. [[Oníṣe:Agbalagba|Agbalagba]] ([[Ọ̀rọ̀ oníṣe:Agbalagba|ọ̀rọ̀]]) 16:32, 18 Oṣù Kẹrin 2024 (UTC)

== Ibanilorukọ jẹ to lagbara ==

Mo yi ayọka ti oloyinbo mọ si Title "The Polytechnic Ibadan" pada si "Polytechnic Ilù Ìbàdàn" ni toripe YORUBA Wikipedia lawa. O jẹ iyanilẹnu pe Iwọ [[Oníṣe:Agbalagba|Agbalagba]] tọka simi gẹgẹ oluṣẹda ayọka, nigba to jẹ pe ayọka yi ti wa tipẹ ti a da silẹ lati ọdọ Olukọwe miran.

Odawipe ọrọ yi o ti kọja oun miran ti koyemi rara. Ibanilorukọ jẹ yi lagabara ti ko si bojumu. [[Oníṣe:Taoheedah|Taoheedah]] ([[Ọ̀rọ̀ oníṣe:Taoheedah|ọ̀rọ̀]]) 17:16, 18 Oṣù Kẹrin 2024 (UTC)

Àtúnyẹ̀wò ní 21:27, 18 Oṣù Igbe 2024

Ẹkáàbọ̀!

Ẹpẹ̀lẹ́ o, Taoheedah,ẹkáàbọ̀ sí Yòrùbá Wikipedia!! Adúpẹ́ fún àfikún yín. Mo lérò wípé ẹ nífẹ́ sí kí ẹ wà níbí. Ẹwo àwọn oun tí a ṣètò sí ìsàlẹ̀ yìí bóyá ó lè wúlò fun yín:

Ẹ jọ̀wọ́ ẹ rántí fi òǹtẹ̀ tẹ oun tí ẹ bá kọ sí ọ̀rọ̀ ojú ewé pẹ̀lú igun mẹ́rin (~~~~); èyí máa gbé orúkọ yín àti déètì jáde. Bí ẹ bá ń fẹ́ ìrànlọ́wọ́ ẹ kàn sí mi, +/-, mo sì máa ràn yín lọ́wọ́, ẹkáàbọ̀! T CellsTalk 09:37, 26 Oṣù Kàrún 2022 (UTC)

Àyọkà

Ẹ kú ìṣe óò! Orúkọ tèmi ni T Cells. Mo ri wípé ẹ ń ṣẹ̀dá àyọkà tí kò si òun kohun níbè bí Ann Mukoro, Prisca Emeafu, Dami Olonisakin àti bẹ́ẹ̀bẹ̀ẹ́ lọ. Ẹ jọ̀wọ́ ẹ kọ àwọn àyọkà yí dáadáa kí ẹ tó ṣẹ̀dá òmíràn. Ẹ ṣeun. T CellsTalk 09:48, 26 Oṣù Kàrún 2022 (UTC)

Àkíyèsí pàtàkì

Ẹ káre Oníṣe:Taoheeda, a kí yín kú iṣẹ́ takuntakun, Mo fẹ́ pè yín sí àkíyèsí pàtàkì lórí àwọn àyọkà yín rí ẹ ń dá sílẹ̀. Ẹ ṣe ògbufọ̀ yín dára dára kí ẹ tó ṣẹ̀dá àwọn àyọkà yí sórí Wikipedia èdè Yorùbá, ó ṣe pàtàkì kí ẹ ṣe èyí fún ìdẹsẹ̀ múlẹ̀ iṣẹ́ gbogbo wa. Ẹ ṣeun púpọ̀.Agbalagba (ọ̀rọ̀) 22:53, 27 Oṣù Kàrún 2022 (UTC)

Àkíyèsí pàtàkì

Oníṣẹ́@Taoheedah, mo ṣàkíyèsí wípé púpọ̀ nínú àwọn àyọkà rẹ tí o kọ sí orí Wikipedia èdè Yorùbá ni wọ́n jẹ́ kíkọ sílẹ̀ pẹ̀lú irinṣẹ́ Google Translation. Mo ma gbà ọ́ níyànjú kí o ṣe àtúnṣe tí ó yẹ sí wọn kí wọ́n lè mọ́yán lórí jù báyí lọ. Lásìkò tí o bá ń ṣe èyí, n ó gbà ọ́ níyànjú kí o má ṣe da àyọkà tuntun míràn sílẹ̀ nítorí kí o lè ráyè kọbi ara sí àwọn àtúnṣe rẹ gbogbo. Àpẹẹrẹ irúfẹ́ àwọn àyọkà bẹ́ẹ̀ ni: Átẹ́gùn Ooru, Ìmúdọ́gba Àyipàdà Ójú Ọjọ́ , Ipà Àyipada Óju Ọjọ ninu Ẹkọ Ọgbin, Aarun Ómi ati Àyipada Óju Ọjọ, Ìṣilọ ati Àyipada lori Àyika Ágbàyè, Ájálù to ṣẹ̀lẹ nipa Ìfómipamọ ti Gusau, Desmond Màjẹkòdùnmì àti bẹ́ẹ̀ bẹ́ẹ̀ lọ. Àwọn ohun tí a ń retí nínú àwọn àtúnṣe rẹ ni:

  1. Ṣíṣàmúlò àkọtọ́ gidi lórí àwọn àyọkà rẹ.
  2. Ṣíṣayípada àwọn ọ̀rọ̀ bíi arákùnrin náà, àti àwọn ohun tó fara pa, ìdí ni pé ìṣọwọ́kọ̀wé yí kò bá ìsọwọ́ kọ ìmọ̀-ọ̀fẹ́ sílẹ̀ mu.
  3. Lílo àwọn àmì ohùn tó yanjú lórí àwọn àyọkà rẹ àti bẹ́ẹ̀ bẹ́ẹ̀ lọ.

Lákòòtán, ìkìlọ̀ tó wà níbẹ̀ ni wípé bí a kò bá rí àtúnṣe tó lọ́ọ̀rìn lóri àwọn àyọkà wọ̀nyí, a ó dárúkọ wọn fún ìparẹ́ kíákíá. Àwọn àyọkà tó mọ́yán lórí la ń fẹ́ lórí Wikipedia èdè Yorùbá; kìí ṣe danda wìì. O ṣeun púpọ̀. Agbalagba (ọ̀rọ̀) 16:32, 18 Oṣù Kẹrin 2024 (UTC)

Ibanilorukọ jẹ to lagbara

Mo yi ayọka ti oloyinbo mọ si Title "The Polytechnic Ibadan" pada si "Polytechnic Ilù Ìbàdàn" ni toripe YORUBA Wikipedia lawa. O jẹ iyanilẹnu pe Iwọ Agbalagba tọka simi gẹgẹ oluṣẹda ayọka, nigba to jẹ pe ayọka yi ti wa tipẹ ti a da silẹ lati ọdọ Olukọwe miran.

Odawipe ọrọ yi o ti kọja oun miran ti koyemi rara. Ibanilorukọ jẹ yi lagabara ti ko si bojumu. Taoheedah (ọ̀rọ̀) 17:16, 18 Oṣù Kẹrin 2024 (UTC)